Ọmọlẹbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọlẹbí

Children are your family/relatives.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-ni-ẹbí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
ni - is
ẹbí - relative, family, kin


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI