Ọmọbọ́rọ̀jí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọbọ́rọ̀jí

The child wakes up with wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-bá-ọrọ̀-jí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
- together with
ọrọ̀ - wealth, riches
- wake up


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Mọbọ́rọ̀jí

Bọ́rọ̀jí