Ọmọ́tẹ́wà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́tẹ́wà

A child suffices for beauty.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is from a Yorùbá belief that physical beauty could fade with age but the beauty a child gives endures a lifetime.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-tó-ẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
tó - suffice for
ẹwà - beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Tẹ́wà