Ọmọ́jọlà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́jọlà
1. The child is greater than wealth. 2. The child enjoys wealth.
Àwọn àlàyé mìíràn
The name is written either as Ọmọjọlá or Ọmọ́jọlà
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-jù-ọlà, ọmọ-jẹ-ọlà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childjù - is more than, mightier than
ọlà - prominence
jẹ - eat, consume
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL