Ọmọ́yẹni
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́yẹni
Child befits one.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-yẹ-ẹni
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childyẹ - befit, fits, is worthy of
ẹni - man, someone
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Yẹni Aníkúlápó-Kútì