Sísọ síta
I'm desirous of a child.
ọmọ-wù-mí
Ó pọ̀ ní: OTHERS
Ọmọ́wùmí
Wùnmí
Wùmí
Ọmáwùmí
Mọ́remí
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.