Ọmọ́wádélé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́wádélé

The child sought (us) home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-wá-dé-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
- to find, to seek out
- arrive at
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Délé

Mọ́wádélé

Wádélé