Ọmọ́wàfọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́wàfọ́lá
The child is here for honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-wà-fún-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childwà - reside, exist
fún - for
ọlá - wealth, affluence, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL