Ọmọ́tóní

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́tóní

A child is a valuable asset.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ́-tó-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
tó - sufficient for
ní - to have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tóní