Ọmọ́rìnọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́rìnọ́lá
The child walks into success.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Ọmọ́rìnsọ́lá.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-rìn-(sí)-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childrìn - walk
sí - into
ọlá - notability, success
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL