Ọmọ́rìnádé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́rìnádé
The child walks into royalty.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-rìn-sí-adé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childrìn - walk
sí - into
adé - crown, royalty
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN
IFE
OTHERS