Ọmọ́pẹ́nnú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́pẹ́nnú
The child took long in the womb.
Àwọn àlàyé mìíràn
This name is typically given with a longer gestation than nine months.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-pẹ́-ní-inú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childpẹ́ - be long, tarry
ní - in
inú - inside of (a person), womb
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL