Ọmọ́nílé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́nílé

The child has a home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-ní-ilé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
ní - have, own
ilé - house, home


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE