Ọmọ́fowókẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́fowókẹ́

The child pampers him/her/us with money.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-fi-owó-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
fi - used
owó - money, cowries
kẹ́ - cherish, care for, pet


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fowókẹ́