Ọmọ́diwúrà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́diwúrà

The child becomes (as precious as) gold.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-di-wúrà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
di - become
wúrà - gold


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Diwúrà