Ọmọèjulérun
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọèjulérun
The child did not allow our household to perish
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-è-jẹ́-ulé-run
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childè - did not
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
ulé - house, home (ilé)
run - ruin, destroy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILAJE