Ọmọ́tinúwẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́tinúwẹ̀

The child that comes clean from the womb.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-ti-inú-wẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
ti - from
inú - stomach, mind, heard, inside, womb
wẹ̀ - bathe, shower, luxuriate


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL