Ọmọ́jọ́lágbé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́jọ́lágbé
The child did not allow our honor perish.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-ò-jẹ́-ọlá-gbé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childò - is not, does not
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
ọlá - wealth/nobility/success
gbé - to perish
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI