Ọmọ́fowówẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́fowówẹ̀

The child used money to bathe.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-fi-owó-wẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
fi - use
owó - money
wẹ̀ - bathe, wash


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE
OYO



Irúurú

Fowówẹ̀