Ọmọ́ṣení

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọmọ́ṣení

The child is good to have.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọmọ-ṣe-é-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọmọ - child
ṣe - make, create
é - it
- have


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣení