Ọmátúyọ̀lé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmátúyọ̀lé
A child is worth rejoicing over.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọma-tú-yọ̀-lé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọma - child (ọmọ)tú - is worth (tó)
yọ̀ - rejoice
lé - be added to, upon
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILAJE