Ọmáṣemọ́yẹ̀n
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmáṣemọ́yẹ̀n
The child makes me joyful.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọma-ṣe-mọ́-ọ̀yẹ̀n
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọma - child (ọmọ)ṣe - make, do, perform
mọ́ - with
ọ̀yẹ̀n - joy, excitement (ọ̀yìn)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO
OWO