Ọlúwamúléró
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlúwamúléró
God is the pillar of the home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-mú-ilé-ró
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godmú - hold
ilé - house, home
ró - stand (dúró)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
AKURE