Ọlúbọ̀wálé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlúbọ̀wálé
The prominent one has returned home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olú-bọ̀-wá-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olú - lord, prominent onebọ̀ - return
wá - come to
ilé - house, home
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EFON