Ọlatọ́mọkún

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlatọ́mọkún

Wealth is sufficient to fill the child.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-tó-ọmọ-kún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
tó - sufficient for
ọmọ - child
kún - fill


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlátọ́mọ