Ọlátúndùn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlátúndùn

Honor is sweet again.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-tún-dùn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, wealth, success, notability
tún - again
dùn - to be sweet


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Látúndùn