Ọlákìtán

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlákìtán

(My) wealth doesn't finish.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-kìí-tán



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, success, notability, nobility
kìí - does not
tán - finish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlákìítán

Ọláìtán

Ọláìítán