Ọlágúnjú

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlágúnjú

Success/wealth is straightforward.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-gún-ojú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, nobility, success
gún - be straight
ojú - face


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Lágúnjú