Ọlágbàmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlágbàmí

Nobility saved me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-gbà-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - nobility, wealth, success, notability
gbà - save, rescue
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Gbàmí