Ọládìran
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọládìran
Honor has become hereditary.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-di-ìran
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - wealth/nobility/successdi - become
ìran - generation(s), genealogy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL