Ọláyímiká

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláyímiká

Wealth surrounds me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-yí-mi-ká



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
yí...ká - surround
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọláyínka

Yímiká

Yínká