Ọláwùmíjù
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọláwùmíjù
I'm most attracted to honour/success.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-wù-mí-jù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - honour, success, wealth, notabilitywù - be attracted to
mí - me
jù - the most
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
