Ọlátóún

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlátóún

Wealth is worth celebrating.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-tó-hún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
tó - suffice for, enough for
hún - rejoice, celebrate


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Tóún