Ọláolúwadémiládé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláolúwadémiládé

The prestige of God has crowned me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-olúwa-dé...ládé-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - prominence, prestige, wealth
olúwa - lord, God
dé...ládé - crown (v)
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
I DO NOT KNOW



Irúurú

Démiládé