Ọláolúwaṣíjibòmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláolúwaṣíjibòmi

God's favour coveres me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-olúwa-ṣí-ìji-bò-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - benefit, favour, fortune, honour
olúwa - lord, God
ṣí - open
ìji - shadow, shade
bò - cover
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
IJEBU



Irúurú

Bòmí

Ṣíjibòmí

Ṣíji