Ọláòkè

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláòkè

Honor of the deity of the hill.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-òkè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honor, wealth
òkè - Deity of the mountain/hill; mountain, hill, Òkè Ìbàdàn


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO