Ọlániwún

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlániwún

(This family of nobility) has someone to rejoice over.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Ọláníihún



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-ní-i-hún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, nobility, success
níi - have him/her
hún - rejoice over


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Láníihún

Ọláníihún