Ọlánẹ́gàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlánẹ́gàn

(Our) nobility has no blemish.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-à-ní-ẹ̀gàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - success, nobility, wealth
à - does not
- to have
ẹ̀gàn - blemish


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Ọlálẹ́gàn