Ọlámitáyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlámitáyọ̀
My honour is worth rejoicing over.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-mi-tó-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - wealth, nobility, honourmi - mine
tó - suffices for
ayọ̀ - joy, happiness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS