Ọlámilékansi

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlámilékansi

My wealth has increased by one once again.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-mi-lé-ìkan-síi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, success
mi - mine
lé - increase
ìkan - one
si/síi - again


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Ọlámilékan

Lékan