Ọlákùsẹ́yìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlákùsẹ́yìn

Nobility/Success remains in the future.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-kù-sí-ẹ̀yìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - nobility, success, wealth
kù - remain
sí - in
ẹ̀yìn - future


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlákùsẹ́hìn