Ọlájíre

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlájíre

(The child of) nobility woke up well.



Àwọn àlàyé mìíràn

Also written as "Ọlájíire".



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-jí-sí-ire



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
jí - woke up
(sí) - to
ire - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL