Ọláfúnmbí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláfúnmbí

Nobility gave me to birth.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Olúfúnmbí, Oyèfúnmbí, Adéfúnmbí, Ọ̀jẹ̀fúnmbí, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-fún-mi-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - success, nobility, notability, wealth
fún - give
mi - me
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fúnmbí