Ọláfisáyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláfisáyọ̀

Wealth completes (my) joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-fi-sí-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
fi - put it
sí - into
ayọ̀ - joy, happiness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OKITIPUPA



Irúurú

Fisáyọ̀