Ọláfẹ́nwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláfẹ́nwá

Wealth sought me here.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-fẹ́-n-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
fẹ́ - love
n - me (mi)
wá - arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọláfẹ́miwá