Ọláelédùà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláelédùà

1. God's blessings/honour. 2. God's benefit.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-elédùà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - prominence, prestige, wealth, honour, benefit
elédùà - Olódùmarè, God almighty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọláolúwa