Ọládìtí
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọládìtí
(Our) honour has become a canopy (for others to rest under).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-di-ìtí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - honour, wealth, success, nobility, notabilitydi - become
ìtí - a tree whose top forms a canopy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL