Ọládọjà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọládọjà
Honour has become the market. Honour has become (famous/widely beloved/boisterous) like the marketplace.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-di-ọjà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - honour, success, nobility, wealthdi - become
ọjà - marketplace
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Rasheed Adéwọ̀lú Ládọjà
former governor of Ọ̀yọ́ State and 44th Olúbàdàn: https://en.wikipedia.org/wiki/Rashidi_Adewolu_Ladoja