Ọlábímpé

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlábímpé

Wealth/Nobility birthed me complete.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Ọlábíntán



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-bí-mi-pé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, nobility
bí - give birth to
mi - me
pé - completely


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bímpé