Ọláṣíjibòmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláṣíjibòmí

Prestige/success/honour covers me in its shade.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-ṣí-ìji-bò-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth, success, prestige, honour
ṣí - open
ìji - shadow, shade
bò - cover
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Ṣíji

Ṣíjibòmí

Bòmí